Tuesday 28 June 2016

Hian Ekiti- 2

(In Ekiti)

All conversations in Ekiti dialect.

Lere: Oga mi, hian lo mo awon arabeyi mu o. Ba ti a mu rice ati ororo ko won se nian shange placard si 'Probe Fayemi ' lesekese!  Oga mi me rirue ri, a fi bi magiki.

Oshoko: Politics is my laife. That's the only game I know. Mo ti ri pe hianrabi feran ijekuje, nu je ki n introduce stomach infrastructure as the pillar of my governance. Ko si hian le da j'oba mi ru. Owo rice, ororo ati jedi nukan nian na mi.

Lere : Oshokooooo!!! Ijaya APC!!! Bet iyan ni a mo ti rian Ekiti nje, bi hian ti a succeed lati convert rian si Rice-eating society si baffle mi. Oga mi, I'm a learner.

Oshoko: Hian ri newspaper loni bei?

Lere: Rara oga mi. Mei r'aye joko rara. Kini hian tun ko pe oga mi se?

Oshoko: Gba, ki hian yen page 15 wo. Mo ti shange logo Zenith. Emi Oshokomole!

Lere: ha ha ha ha.....oga mi pa won o!!! Oshoko!!!!! Raluway ti n run won jegejege! Yerepe ti a nibikan a farakan! Oshoko ti a d'osa! Talo n je jagaban?!

No comments:

Post a Comment