Wednesday 4 January 2017

The parable of MAJE

And here is the summary of the matter:

1. MAJE ki èmí Olorun ma dari re nigbagbogbo. Ona ti o to l'oju re le je ibi iparun ni yio gbe o de.

2. MAJE ki ailarojinle ati adun awon ohun asan aye ti kii t'ójó, bo o l'oju lati ri awon àmìn ti n pe akiyesi re si awon ewu to wa ninu awon igbese ti o n gbe.

3. MAJE ohunkohun ti o ba ma yo ago ara re lenu. Bi o ti wu ki won fi ododo se l'oso to, ni amojukuro. Bi o ti wu ki won rò ó to lati gba, ko ja'le.

Notes:

1. MAJE: To be
2. MAJE: Not to be
3: MAJE: Refuse

AV

(Decoding committee over to you 😀)

No comments:

Post a Comment