Tuesday 17 January 2017

ARISTOcratic Authority

- Wos! Pe omo yen wa funmi.

- Omo ewo?

- Iyen...iyen...ehn, iyen...to wa l'egbe yen. So fun wipe awa ARISTOcratic authority lo n pe.

- Iyawo mi ni. A se se marry ni.

- And so? Se won sese n marry ni? Awon to ti marry 8yrs gan a si mu won bale.
....OK fi sile...fi sile. 
O nso wipe o ma le. Awon wo lo fe le mo? Se emi abi eyin?

- Eyin.

- Emi?

- Beeni. Eyin.

- Se omo ilu yi de ni Iwo yi?

- S'emi?

- Yes Iwo. Are you an indigene?

- Beeni.

- Indigene n'iwo yi? O ma se o! O ye ko si ni little respect for ARISTOcratic authourity, no matter what. Bi mo se ni ko pe wa funmi yen, even though o le sese marry, wa so wipe; ah oga o, e joo o...e ma je ka se be o. A nse honeymoon lowo ni o. O n wa nkorin wipe yio le koko l'ote yi. Ta lo fe le mo?  Ko le le mo mi now. I demand an apology from you.

AV

No comments:

Post a Comment