Ma se wa l'oko to n sin iyawo r'ele àlè nitori atije.
F'owo jinki wa Yarabi, ka r'oun mu s'ike aya at'omo.
Nibi egbe wa ti n na'wo, ma je a b'awon n'agidi.
Ma je ka rin Maili meji ninu yara l'ojo bukata ba de'le lati gbo
Ma se wa l'okunrin bantie,
To je pe kòkòrò abe nikan l'ani banti
Fi kókóró aye naa si wa l'apo.
Owo la fi n s'aye.
Buruji ni won fi n ye'ni si l'awujo
Ko s'owo, ko s'iyi.
Ko s'owo, ko s'aponle.
©AV
No comments:
Post a Comment