Thursday 11 September 2014

Prayers for the detractors

Do you know that Hamman wasn't even aware that Modecai don't normally join the rest of the people to greet him whenever he's walking past. Awon kan ni won ko ara won jo ti won lo so fun.

They said "oga, do you know that anytime you are coming and all of us are running helter-skelter, Modeccai don't bother.....you need to punish him"

Awon enia kan wa bee. Awon abaniworan-ba o ri da. Awon igbimo olufisun. Awon a bat'eni je. Awon onimodarun enia.

Mo wa soro ase jade si gbogbo eyin wonyi:
Eyin te n f'imi sun lodo awon to ni agbara lati fi ara ni mi,
Eyin ti e n f'imi sun lodo awon to wa n'ipo lati gbese le eto mi,
Eyin ti e n ba mi je lodo awon to ye ko se mi loore

Eyi ni idajo yin:
Lati oni lo, ki ohun (voice) yin bere si kan (sour) leti gbogbo eda aye.

Mo fi aso ete, abuku, ati ibaje wo yin.

Mo fi ami ikorira si yin lara

E o tun niyi mo.

Paripari e ni yi:

Gbogbo ibaje mi ti e ti wa se sehin, ko bere si ja si igbega fun mi.
Gbogbo ibiti e ro mi ka kiri de, ko di ipolongo oriire funmi.

Bee ni yio ri. Eyi ti mo wi loni, ase orun ti gun. O de ti se bee!

Amin!

No comments:

Post a Comment