Thursday, 10 December 2015

The Parable of the Talents

THE PARABLE OF THE TALENTS

Since the yardstick used in measuring a fulfilled/fulfilling ministry has changed from the number of souls won for Christ to the number of church branches and assets portfolio, men of God are now more determined than ever to go to any length inorder to maintain a top position on the ratings.

You have 30 church members; aye awon 30 yen gan o ti lojutu talkless of them having any hope of making heaven, yet you are disturbing God to increase them to 3,000.

Se oro salvation naa le n ba kiri, abi calculation?

What about the parable of the talents you always preach about? That don't apply to you abi? Ti yin ye yin o, Olorun naa de mo nkan to nse. He has given everyone according to their abilities, and He's expecting you to work on what He has given you to increase it.

Instead of you working on the 30 to make their lives become attractive enough to draw souls into God's kingdom , se le ko church leaflets le won lowo bi awon to nta insurance policy, e wa da won si town centre ki won lo ma wa customers wa. Ti awon naa ba de orita tan, they'll meet groups from other churches who are also there for similar pupose.
Tomato Plum lasan ni a ni ka sare jade lo ra, leaflets different churches merin la ko pada wa sile! That's not evangelism! That's marketing!

The people followed Jesus Christ everywhere he went because his life was attractive. Won ri ami lara Jesu Kristi ti o mu won gbaagbo - John 6:2.
Sugbon awon 30 te ran jade o ni ami kankan lati fi han! Aye awon ti won fe lo pin leaflets fun gan san ju ti won lo, so they are looking at them thinking what you are even offering ain't working for you, so why should we accept it?

Aye to ba lojutu nikan lo n kede igbala!

You don't even know the houses of these 30 members, how can you know 3000? You don't know or share in their personal pains and burdens, how can you do for 3,000? These 30 who are the pillars of your ministry are still weak in faith, how can they support the 3000?

Whose interest are you pursuing- God's kingdom or your own empire?

Go back and work on the 30 members God has put in your care. Change your prayers from 'Lord, give me more members...' to 'O Lord, do not let any of these ones you have given me be lost to the world. Make their lives attractive to draw more souls into your kingdom...'

These 30 are your 1 TALENT that the master has given you to trade with. Don't bury it because you consider it too little! Work and multiply it. Empower the 30 to go out there and affect another 30. 

Matthew 25:14-30

AV

Different gifts, different callings

Kirk Franklin o ni ogo ju mi lo, ogo wa kan yato ni.
Nkan ti mo le se, ko le se. Nkan ti ohun naa de le se, emi naa o le se.

Bo se gba award to yen, ti won ba pe ko wa k'orin isoji, walahi awon enia ma sun ni. Ti won ba de pe emi naa ki nwa ko 'Yur-Yur Gospel', o likely ki n fumble.

So if you have a music concert and you cannot afford Kirk Franklin's charges, e wa wo wipe afterall won o ti nominate mi fun BET award ri but i'm equally a good singer, and you can just put £50 inside envelope to invite me to perform like Kirk, eyin gangan le f'owo ara yin ba concert yin je o.

There's every likelihood that i won't turn up because ogo ti mo ni ju £50 lo, but if at all i honour the invite (maybe after meeting my demands), i'll only perform to my strength and not to Kirk's.

Ti e ba wa nmu note after notes wa ba mi lori stage tabi ti e nran awon protocols si mi, on what you want me to do, ma ma ya awon notes yen ni, mo de ma ma le awon protocols yin danu.

Samuel was a prophet, ohun lo ye ko rubo. The moment you are urging Saul to carry out the role of Samuel, e fe fa ijoba e ya niyen. Emi o de ni gba ki anybody fa ijoba mi ya.

So if Kirk can be paid thousand of dollars and lodged in a 5-star hotel, for a 10-minute performance, why can't i be given the same treatment? Can he sing to raise the dead? Is it because i don't have as many awards? Is it because i don't put on lipstick or eye shadow? Is it because i sing in a different language?

We should learn to respect and celebrate individual's gifts and callings.
Gbogbo wa la ni ogo, sugbon enia nw'oju, Olorun lo nwo okan.

Phonetics Made Easy

Are you a Nigerian?
Fed up of your local accent?
Preparing to travel home for Xmas and want to speak like a Britico when you get there?

I have good news for you. Learn to speak phonetics in 3 simple steps:

1. Insert 'R' in the middle or at the end of every word. The exception is when 'T' ends a word; Don't pronounce the ' T'. Make it silent.

2. Pretend you have saliva in your mouth while trying to speak.

3. Lift your chin, tilt your head to the side of your choice (preferably to the left), breath only at the beginning of a sentence and use that same breath to complete all you have to say.

E.g:

I went to Yaba to eat.

Will be:

I wernt tor Yarbar tor ea

You gerrit?

Now Practice.....practice......practice.

Congrats and welcome to Brihish arksent bloween club.

Super Mega Conventions

The song of late Bayo Adegboyega comes to mind this morning:
'Ododo ni ngbe orile ede leke, ka f'imo s'okan ka jo gbe ogo ile yi ga'.
Only truth uplifts the glory of a nation, let's come united to lift the glory of the nation high.

Experience, Shiloh, Holy Ghost conference and all other super mega meetings are in progress, with the various venues filled to the maximum capacity, yet nothing works in the country.

Worshippers, after each day's event, go back home to sleep in darkness, turn up to work the next day expecting somebody to bribe them before they do the job they are being paid for, tear some people down for themselves to rise, sabotage the efforts of the government, fail to tell the truth, commit all other acts of wickedness, and then turn up in the evening to continue the one-week long annual event, lifting up 'holy' hands, gyrating to the beats of the worldship, and laughing to the jokes of the invited comedians.

At the end of the whole charade, their lives remain the same, the country get worse, and some people smile to the bank.

'Let's lift up our voices to pray that God should heal Nigeria', but some of the cankerworms eating up the country are special guests in these same programmes, sited in reserved bullet proof cubicles. Their hosts cannot tell them the truth because all na padi-padi arrangement.

The only time you'll see equal number of crowd gather here in the UK is during a football match, yet the system works far better.
The know for a fact that God don't  fix light, God don't fight corruption, God don't fix systems. These things are for them as individuals to sort out!
They understand and pratice accountability, integrity and fairness even without congregating in any place of worship.

What is the purpose of attending these huge events when no one practices what is being preached? The wicked is still wicked. The unjust is unjust still. Evil still abound in the land.

Sunday, 27 September 2015

Iranlowo

OLUWA, JE KI AANU RE GBA IBITI MO WA KOJA

Opolopo wa lo ma n dide lojoojumo lati wa iranlowo lo, tabi lati ke si awon enia lati wa ran wa lowo. Kayefi to wa nibe ni wipe, awon iranlowo ti a ma nri gba je eyiti o tun ma nda wa pada sipo ti a tun ti nilo iranlowo.

Ojoojumo ni Batimeu, afoju, ma nri iranlowo gba lodo awon to ma nse atona re lo si eba ona lati se agbe. Awon to ba nkoja tun je awon alaanu miran to tun ma nran lowo nipa fifun ni toro-kobo ti won ba ni ki o fi jeun.
Bi o ba di owo ojo'ro, awon oluranlowo miran a tun se atona re pada sile.
O nri iranlowo gba lojoojumo sugbon, itan re ko yipada. Gbogbo igba naa lo tun nba ara re pada nipo ti yio ti nilo iranlowo.

Iranlowo ti ko ba yi itan aye eni pada kii se iranlowo.

Okunrin abirun kan wa leti odo Bethesda fun odun mejidinlogoji (38years). Oun naa kuku nri iranlowo gba- o nri awon alaanu ti won nfun lounje, bi bee ko, ko le lo iye odun yi lai jeun-yio ti gbemi mi. Sungbon, iranlowo ti oun naa nri yi ko yi itan re pada. Oun naa si nba ara re lojoojumo ni ipo ti yio tun ti nilo iranlowo.

Eyi ni yio tun mu mi so lekaan si wipe iranlowo ti ko ba yi itan aye eni pada kii se iranlowo.

Lojo kan, awon atona Batimeu, afoju, tun se atona re lo si ipo ti yio tun ti lo wa iranlowo gege bi ise re, sugbon ojo yi yato! Aanu gba odo re koja. JESU KRISTI GBA ODO RE KOJA.

Lojo yi, Batimeu kigbe bi ko ti kigbe fun iranlowo ri. Lojo yi ko bere fun iranlowo, O BERE FUN AANU. O bere fun aanu ti nyi itan aye eni pada. O bere fun ohun kan ti ko ni je ko tun pada sipo ti o ma n ba ara re nigbogbo igba lati wa iranlowo ti ko ba ni kale mo. Lojo yi, o bere fun ohun to je logun ju-  o ni "KI EMI KI O LE RIRAN"

Lehin ti awon to ma n saanu fun okunrin abirun yi fun ni ounje tan lojo yi, oun naa n reti ki ojo na lo bakanna bi o ti ma nri ni opolopo odun. Sugbon, lojo yi, aanu gba odo oun naa koja. Oun o ti e pariwo, aanu kan sawari re laarin ogunlogo enia ni. O ri iranlowo to gaju ounje lo. O ba aanu to nyi itan aye enia pada pade! Oun naa di eni ti o le kuro lojukan lehin opolopo odun ti o ti fi sofo! ITAN RE YI PADA!

Iranlowo ju iranlowo lo!
Eniti a bu omi fun ki o fi re ongbe yato si eniti a gbe kanga fun lati ma bu mu nigbakugba ti o ba fe.

Eyi lo mu mi gba adura yi wipe:

"Oluwa, je ki aanu re gba ibiti mo wa koja!
Awon iranlowo ti mo nri gba lowolowo bayi nda mi pada sipo lati tun wa iranlowo ni. Dakun wa fi iranlowo ti n yi itan aye eni pada ba emi naa pade!"

Bi oro yi ba kan iwo naa lara, o le gba adura yi bakanna.

AV

Ayekooto Jeremy 'Jagaban' Corbyn

The world hates a man with gut.
The world loathes a man that lives by his principles.
They make friends with a liar and adore the hypocrite
They just love it when we all 'sleep facing the same position'.

'Jeremy Corbyn did not sing the national anthem. He's unpatriotic and a disgrace'. Really? Is that all there is to patriotism? Singing of national anthem? What of pushing policies that'll help the people and the country become better?
Who knows what was going in his mind while he stayed slient. Maybe one of the things he'll be pushing for if he ever becomes the prime minister, is a better and more representative national anthem which will mention the country's values, and the achievement of those who have made this country great.

'He's always slouched in casual clothes. He's not fit to be a leader'.  Really?

I think i'm beginning to take special interest in this man- his gut, style and principles. I think he's another version of Boris Jonhson. They sometimes don't look the part, but they perform-and that's all that matters.

Netflix ati chill

IKEDE PATAKI

Iroyin ti fi to wa leti wipe awon omo ìyá meji kan ti n soro kiri ilu bi oká bayi, pelu kiko ibasun fun  gbogbo obinrin ti o ba wo panpe won, ti won a si ri daju wipe o d'oyun.

Oruko awon mejeeji yi ni NETFLIX ati CHILL. Adape won miran a tun ma je NETFLIX AND CHILL.

Awon odaju meji yi ko bowo fun iyawo oba, beeni won ko naani omo ijoye. Won o mo abileko yato si olomoge.
Opolopo ajosepo ololufe ni won ti daru beeni, won ti so awon odomobinrin to sese n balaga sipo oloyun laitojo.

A ro gbogbo eniyan lati kilo fun awon aya won, aburo won l'obinrin ati omobinrin won lati sora fun awon ajanilole-ara mejeeji yi titi owo awon agbofinro yio fi te won.

Eniti ko ba n'ise ko lo wa ise se nitori wipe awon to sa ba ma nko si won lowo ni awon ti owo won dile. Eyi fi daju wipe ooto ni oro ojogbon Albert Eistein (1876) to so wipe 'owo to ba dile ni esu nwa ise fun'.

E ku faaji opin ose!

AV