Monday 23 February 2015

Missionary only

Won ti salaye fun wa wipe 'Missionary style' nikan l'Olorun f'owo si o.

Gbogbo eyin l'oko l'aya ti orisirisi ere buruku mbe lowo yin, won ni ina orun apaadi ti won fi sufuru (Sulphur) da le fi nsere o.

Won ni Olorun o fe ki eyin okunrin ma ba aya lajosepo lati ehin. E kii s'aja o, tabi eshin.

Won ni eyin ti e ma nso iyawo yin l'apa ati ese mo beedi, ti e o wa ma ko bilala bo won haihai latari ibasun, won ni ke ja'wo.

Eyin aya to je wipe oke leyin naa ma nfe duro si, eyin le fe ma pe'se, won ni Olorun o ran yin o. Won ni ki e gba okunrin ti o je olori laaye ko duro soke. Eyin ko lolori o...be o ba sokale, won ni orun apaadi le fi nsere o.

Eyin ti e so kini oko yin di carrot tabi ice lolly, won ni ki e ja'wo o! Nkan ti Olorun da fun ni ki e je ko je. Won ni asilo le ran yin lo si orun apaadi o.

Make i face my work #uche

No comments:

Post a Comment