Saturday 14 February 2015

Pray for the peace of Jerusalem

When you pray for God's blessings, remember your family members too in your prayers, and that God should bless the hustles of your friends too.

You know why?

Olowo kan laarin olosi mefa, baba nla olosi loun naa o!

Lakoko naa, won a fi bukata ba ti e je.....

Awon to de ma korira e for no just cause naa de ma wa.....

Bee l'awon kan ma ma sare kiri wipe ki tie baje ki o le pada si square one.

Ona to fe fi gbadun owo e da?

Eleyi gangan ni itumo 'Gbadura fun alaafia Jerusalem...'
Ti Jerusalem won o ba ni isinmi, won o ni je ki iwo gan o ni isinmi.

No comments:

Post a Comment