Wednesday 27 May 2015

OWO SE KOKO

Opolopo spiritual problems ta ma n so wipe a ni yi gan, are not spiritual problems. Ko s'owo ni!
Ailowo lowo de ma nfa erokero. Erokero ma nfa alakala. Ti alakala ba de ti wole de isoro de niyen. O di ki awon onigbagbo kukuru ma sare kiri fun deliverance. Bi won se nmu olive oil ni won nmu miss paris, bee naa ni won nla epo pupa, ti won tun nfi edun ara je ekuru.

E ma je ka tan ara wa, ailowo lowo lo fa gbogbo ratirati yen....


Infact ti e ba tun se iwadi headache ati monthly migraine to ma nse opolopo ninu wa gan, ailowo lowo buruku yen la ma ba nidi e.

Owo se koko.
Owo la fi n s'aye.
Owo la fi nse fuja lawujo.
Ko s'owo ko s'iyi.
Ko s'owo s'ore.
Ko s'owo ko s'aponle.
Ko s'owo ko s'alaafia.
Ko s'owo ko si oorun.

Yawns.....

No comments:

Post a Comment